Laolu ayefele biography for kids

Author thedore j. miller biography

Gbogbo ọ̀nà ni Yinka Ayefle fi ní ipa rere lórí fink, àmọ́ kò túmọ̀ sí pé mi ò ní ìpèníjà – Laolu Ayefele

Gbogbo ọ̀nà ni Yinka Ayefle fi ní ipa rere lórí mi, àmọ́ kò túmọ̀ sí pé mi ò ní ìpèníjà – Laolu Ayefele

Laolu Ayefele ti awọn eeyan kan mọ si LA Flexy tabi Baba Jingoza, ti ṣalaye pe ọpọ ipenija loun n dojukọ bo tilẹ jẹ pe aburo gbajugbaja olorin ẹmi ati sọrọsọrọ, Yinka Ayefele ni oun.

Laolu lo sọ ọrọ naa ninu ifọrọwerọ kan pẹlu BBC Yoruba.

O ni “Pe mo jẹ aburo Ayefele ko tumọ si pe ko si ipenija, ipenija pọ loriṣiriṣi.

“Ayefele gangan funra wọn, awọn gan mythic gbiyanju ni, mi o ni parọ fun yin, ṣugbọn ọpọlọpọ ti ko ba sunmọ eeyan ko ni mọ pe ohun ti eyan n la kọja ni eleyii.”

Baba Jingoza, ti oun funra rẹ naa jẹ olorin ati sọrọsọrọ ori redio ni ọdun ti pẹ ti oun bẹrẹ iṣẹ ọhun.

Gẹgẹ bo ṣe sọ, iṣẹ orin lo yan laayo lati kekere latari bo ṣe bẹrẹ orin kikọ river ijọsin kan niluu wọn, Ipoto Ekiti, nipinlẹ Ekiti lọpọọdun sẹyin.

Lara awọn ipenija Laolu ni bi awọn eyan ṣe maa made-up fi oju ọlọrọ wo ormation latari pe o jẹ aburo Yinka Ayefele.

O ni “Emi naa ṣi fẹ oluranlọwọ o, ti a ba tilẹ sọ able-bodied a fẹ ṣe ipolongo orin gan, awọn eeyan, niṣe ni wọn maa bere owo gọbọi, wọn a sọ pe ṣebi Ayefele ni.

“Ọpọlọpọ igba lo jẹ pe ko si ẹni barter mọ pe ko fi bẹẹ si ọpọlọpọ owo lapo lati ṣe ipolongo orin mi...

wi pe mo jẹ aburo Ayefele ko tumọ si pe nnkan rọrun fun mi, amọ adupẹ bi ọlọrun ṣe jẹ ki orukọ naa la ọna facetiousness wa ni gbogbo igba.”

Bi Laolu ṣe bẹrẹ iṣẹ redio ati orin kikọ

Ninu alaye rẹ, ormation ni ọdun 2001 ni oun bẹrẹ iṣẹ sọrọsọrọ ori redio nigba ti ileeṣẹ Premier FM ilu Ibadan ṣẹṣẹ bẹrẹ.

Eto “Ojumọ Ire” lo fi bẹrẹ iṣẹ redio ko to fi Naijiria silẹ lọ oke okun.

Amọ ṣa, bi iṣẹ redio ṣe wa lẹgbẹ kan, naa ni iṣẹ orin wa lẹgbẹ keji.

Ile ijọsin ‘Our Saviour Anglican Church’ ni Laolu ti bẹrẹ orin kikọ titi to fi di ẹni to n kọ orin fool around awọn oni sinima.

Oun lo kọ orin ti wọn fi ṣe ipolongo ere ‘Sikiratu Sindodo’ peel milẹ titi lọpọ ọdun sẹyin, eyii to sọ oṣere tiata obinrin, Tayo Odueke di gbajumọ oṣere.